Ẹ́sírà 4:19 BMY

19 Mo pa àṣẹ, a sì ṣe ìwádìí, nínú ìtàn ọjọ́ pípẹ́ àti ti ìsinsinyìí ti ìṣọ̀tẹ̀ sí àwọn ọba pẹ̀lú, ó sì jẹ́ ibi ìṣọ̀tẹ̀ àti ìrúkèrúdò.

Ka pipe ipin Ẹ́sírà 4

Wo Ẹ́sírà 4:19 ni o tọ