21 Nísinsìn yìí pa àṣẹ fún àwọn ọkùnrin yìí láti dá iṣẹ́ dúró, kí a má ṣe tún ìlú náà kọ títí èmi yóò fi pàṣẹ.
Ka pipe ipin Ẹ́sírà 4
Wo Ẹ́sírà 4:21 ni o tọ