24 Báyìí, iṣẹ́ lórí ilé Ọlọ́run ní Jérúsálẹ́mù wá sí ìdúró jẹ́ẹ́ títí di ọdún kejì ìjọba Dáríúsì ọba Páṣíà.
Ka pipe ipin Ẹ́sírà 4
Wo Ẹ́sírà 4:24 ni o tọ