Ẹ́sírà 4:4 BMY

4 Nígbà náà ni àwọn ènìyàn ilẹ̀ náà mú ọwọ́ àwọn ènìyàn Júdà rọ, wọ́n sì dẹ́rù bá wọ́n ní ti kíkọ́ ilé náà.

Ka pipe ipin Ẹ́sírà 4

Wo Ẹ́sírà 4:4 ni o tọ