Ẹ́sírà 5:11 BMY

11 Èyí ni ìdáhùn tí wọ́n fún wa:Àwa ni ìránṣẹ́ Ọlọ́run ọ̀run àti ayé, àwa sì ń tún tẹ́ḿpìlì ilé Olúwa tí a ti kọ́ ní ọ̀pọ̀ ọdún sẹ́yìn kọ́, èyí tí ọba olókìkí kan ní Ísírẹ́lì kọ́, tí ó sì parí i rẹ̀.

Ka pipe ipin Ẹ́sírà 5

Wo Ẹ́sírà 5:11 ni o tọ