Ẹ́sírà 5:6 BMY

6 Èyí ni ẹ̀dà lẹ́tà tí Tétanáì, olórí agbégbé Yúfúrátè àti Ṣétarì-Bóṣénáì àti àwọn ẹlẹ́gbẹ́ ẹ wọn. Àwọn olóyè ti agbégbé Yúfúrátè, fi ránṣẹ́ sí ọba Dáríúsì.

Ka pipe ipin Ẹ́sírà 5

Wo Ẹ́sírà 5:6 ni o tọ