Ẹ́sírà 6:6 BMY

6 Nítorí náà, kí ìwọ, Táténíà Baálẹ̀ agbègbè Yúfúrátè àti Ṣétarì-Bóṣénáì àti àwọn ẹlẹ́gbẹ́ yín, àwọn ìjòyè ti agbègbè náà, kúrò níbẹ̀.

Ka pipe ipin Ẹ́sírà 6

Wo Ẹ́sírà 6:6 ni o tọ