Ẹ́sírà 7:27 BMY

27 Olùbùkún ni Olúwa, Ọlọ́run àwọn baba wa, ẹni tí ó fi sí ọkàn ọba láti mú ọla wá sí ilé Olúwa ní Jérúsálẹ́mù ní ọ̀nà yìí.

Ka pipe ipin Ẹ́sírà 7

Wo Ẹ́sírà 7:27 ni o tọ