19 Àti Ásábáyà, pẹ̀lú Jésáíyà láti ìran Mérárì, pẹ̀lú àwọn arákùnrin rẹ àti àwọn ọmọ wọ́n jẹ́ ogún (20) ọkùnrin.
Ka pipe ipin Ẹ́sírà 8
Wo Ẹ́sírà 8:19 ni o tọ