Ẹ́sírà 8:23 BMY

23 Bẹ́ẹ̀ ni a sì gbààwẹ̀, a sì bẹ̀bẹ̀ fún èyí lọ́dọ̀ Ọlọ́run wa, òun sì gbọ́ àdúrà wa.

Ka pipe ipin Ẹ́sírà 8

Wo Ẹ́sírà 8:23 ni o tọ