Ẹ́sírà 8:25 BMY

25 Mo sì fi òṣùwọ̀n wọn ọrẹ fàdákà àti wúrà àti àwọn ohun èlò tí ọba àti àwọn ìgbìmọ̀, awọn ìjòyè àti gbogbo ọmọ Ísírẹ́lì tí ó wà níbẹ̀ gbe fi sílẹ̀ fún ilé Ọlọ́run wa.

Ka pipe ipin Ẹ́sírà 8

Wo Ẹ́sírà 8:25 ni o tọ