Ẹ́sírà 8:30 BMY

30 Nígbà náà ni àwọn àlùfáà àti àwọn Léfì gba fàdákà àti wúrà àti àwọn ohun èlò mímọ́ ti a ti wọ̀n jáde fún kíkó lọ sí ilé Ọlọ́run wa ní Jérúsálẹ́mù.

Ka pipe ipin Ẹ́sírà 8

Wo Ẹ́sírà 8:30 ni o tọ