Ẹ́sírà 9:3 BMY

3 Nígbà tí mo gbọ́ èyí, mo fa àwọ̀tẹ́lẹ̀ àti agbádá mi ya, mo ja irun orí àti irungbọ̀n mi, mo sì jókòó ní ìbànújẹ́.

Ka pipe ipin Ẹ́sírà 9

Wo Ẹ́sírà 9:3 ni o tọ