Jónà 1:16 BMY

16 Nígbà náà ni àwọn ọkùnrin náà bẹ̀rù Olúwa gidigidi, wọn si rúbọ sí Olúwa, wọ́n sì jẹ́ ẹ̀jẹ́.

Ka pipe ipin Jónà 1

Wo Jónà 1:16 ni o tọ