Jónà 1:17 BMY

17 Ṣùgbọ́n Olúwa ti pèṣè ẹja ńlá kan láti gbé Jónà mì. Jónà sì wà nínú ẹja náà ni ọ̀sán mẹ́ta àti òru mẹ́ta.

Ka pipe ipin Jónà 1

Wo Jónà 1:17 ni o tọ