Léfítíkù 14:16 BMY

16 Yóò sì ti ìka ìfábẹ̀ ọ̀tún rẹ̀ bọ inú òróró àtẹ́lẹwọ́ rẹ̀, yóò sì wọ́n díẹ̀ nínú rẹ̀ níwájú Olúwa nígbà méje.

Ka pipe ipin Léfítíkù 14

Wo Léfítíkù 14:16 ni o tọ