Léfítíkù 14:19 BMY

19 “Àlùfáà yóò sì rú ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀: yóò ṣe ètùtù fún ẹni tí a ó wẹ̀ kúrò nínú àìmọ́ rẹ̀, lẹ́yìn náà àlùfáà yóò pa ẹran ọrẹ ẹbọ sísun.

Ka pipe ipin Léfítíkù 14

Wo Léfítíkù 14:19 ni o tọ