Léfítíkù 14:29 BMY

29 Kí àlùfáà fi ìyókù nínú òróró ọwọ́ rẹ̀ sí orí ẹni náà tí a ń ṣe ìwẹ̀nùmọ́ fún: láti ṣe ètùtù fún un ní ìwájú Olúwa.

Ka pipe ipin Léfítíkù 14

Wo Léfítíkù 14:29 ni o tọ