Léfítíkù 14:37 BMY

37 Yóò yẹ àrùn náà wò, bí àrùn náà bá ti wà lára ògiri ilé náà nípa àmì àwọ̀ ewé tàbí àmì pupa tí ó sì jinlẹ̀, ju ara ògiri lọ.

Ka pipe ipin Léfítíkù 14

Wo Léfítíkù 14:37 ni o tọ