Léfítíkù 14:45 BMY

45 Wíwó ni kí a wó o, gbogbo òkúta ilé náà, àwọn igi àti gbogbo ohun tí a fi rẹ́ ẹ ni kí a kó jáde nínú ìlú sí ibi tí a kà sí àìmọ́.

Ka pipe ipin Léfítíkù 14

Wo Léfítíkù 14:45 ni o tọ