Léfítíkù 14:48 BMY

48 “Bí àlùfáà bá wá yẹ̀ ẹ́ wò tí àrùn náà kò gbilẹ̀ mọ́ lẹ́yìn tí a ti rẹ́ ilé náà: kí àlùfáà pe ilé náà ní mímọ́, torí pé àrùn náà ti lọ.

Ka pipe ipin Léfítíkù 14

Wo Léfítíkù 14:48 ni o tọ