Léfítíkù 14:53 BMY

53 Kí àlùfáà ju ààyè ẹyẹ náà sílẹ̀ lẹ́yìn ìlú. Báyìí ni yóò ṣe ètùtù fún ilé náà. Ilé náà yóò sì mọ́.”

Ka pipe ipin Léfítíkù 14

Wo Léfítíkù 14:53 ni o tọ