Léfítíkù 15:30 BMY

30 Kí àlùfáà fi ọ̀kan rúbọ ẹ̀ṣẹ̀ àti èkejì fún ẹbọ sísun. Báyìí ni yóò ṣe ètùtù fún un, níwájú Olúwa fún àìmọ́ ìsun ẹ̀jẹ̀ rẹ̀.

Ka pipe ipin Léfítíkù 15

Wo Léfítíkù 15:30 ni o tọ