Léfítíkù 15:8 BMY

8 “ ‘Bí ẹni tí ó ní ìṣunjáde bá tu itọ́ sí ẹni tí ó mọ́ lára, ẹni tí ó mọ́ náà gbọdọ̀ fọ aṣọ rẹ̀ kí ó sì wẹ̀: yóò sì wà nípò àìmọ́ títí di ìrọ̀lẹ́.

Ka pipe ipin Léfítíkù 15

Wo Léfítíkù 15:8 ni o tọ