Léfítíkù 2:12 BMY

12 Ẹ lè mú wọn wá fún Olúwa gẹ́gẹ́ bí ọrẹ àkọ́so ṣùgbọ́n ẹ kò gbọdọ̀ mú wọn wá sórí pẹpẹ gẹ́gẹ́ bí òórùn dídùn.

Ka pipe ipin Léfítíkù 2

Wo Léfítíkù 2:12 ni o tọ