Léfítíkù 20:14 BMY

14 “ ‘Bí ọkùnrin kan bá fẹ́ tìyatọmọ papọ̀: ìwà búburú ni èyí: iná ni kí ẹ fi sun wọ́n, òun àti àwọn méjèèjì, kí ìwà búburú má baà gbilẹ̀ láàrin yín.

Ka pipe ipin Léfítíkù 20

Wo Léfítíkù 20:14 ni o tọ