Léfítíkù 20:20 BMY

20 “ ‘Bí ọkùnrin kan bá bá aya arákùnrin bàbá rẹ̀ lòpọ̀ ó ti tàbùkù arákùnrin bàbá rẹ̀. A ó jẹ wọ́n ní ìyà; wọn yóò sì kú láìlọ́mọ.

Ka pipe ipin Léfítíkù 20

Wo Léfítíkù 20:20 ni o tọ