Léfítíkù 20:23 BMY

23 Ẹ má ṣe tẹ̀lé àṣà àwọn orílẹ̀ èdè tí mo lé jáde níwájú yín torí pé gbogbo nǹkan wọ̀nyí ni wọ́n ń ṣe, tí mo kóríra wọn.

Ka pipe ipin Léfítíkù 20

Wo Léfítíkù 20:23 ni o tọ