26 Ẹ gbọdọ̀ jẹ́ mímọ́ fún mi torí pé èmi Olúwa fẹ́ mímọ́. Mó sì ti yà yín kúrò nínú àwọn orílẹ̀ èdè yòókù kí ẹ le jẹ́ tèmi.
Ka pipe ipin Léfítíkù 20
Wo Léfítíkù 20:26 ni o tọ