1 Olúwa sọ fún Mósè wí pe, “Bá àwọn àlùfáà tí wọ́n jẹ́ ọmọ Árónì sọ̀rọ̀, kí o sì sọ fún wọn pé: ‘Ẹnikẹ́ni nínú wọn kò gbọdọ̀ sọ ara rẹ̀ di aláìmọ́ nítorí àwọn ènìyàn wọn tí ó kù.
Ka pipe ipin Léfítíkù 21
Wo Léfítíkù 21:1 ni o tọ