Léfítíkù 22:10 BMY

10 “ ‘Kò sí ẹnikẹ́ni lẹ́yìn ìdílé àlùfáà tí ó le jẹ ọrẹ mímọ́ náà, bẹ́ẹ̀ ni, àlejò àlùfáà tàbí alágbàṣe rẹ̀ kò le jẹ ẹ́.

Ka pipe ipin Léfítíkù 22

Wo Léfítíkù 22:10 ni o tọ