Léfítíkù 22:29 BMY

29 “Nígbà tí ẹ bá rú ẹbọ ọpẹ́ sí Olúwa, ẹ rú u ní ọ̀nà tí yóò fí jẹ́ ìtẹ́wọ́gbà fún yín.

Ka pipe ipin Léfítíkù 22

Wo Léfítíkù 22:29 ni o tọ