Léfítíkù 22:8 BMY

8 Kò gbọdọ̀ jẹ ohunkóhun tí ó bá ti kú sílẹ̀, tàbí tí ẹranko fàya, kí ó sì tipa bẹ́ẹ̀ di aláìmọ́. Èmi ni Olúwa.

Ka pipe ipin Léfítíkù 22

Wo Léfítíkù 22:8 ni o tọ