Léfítíkù 24:7 BMY

7 Ẹ fi ojúlówó tùràrí sí ọnà kọ̀ọ̀kan, gẹ́gẹ́ bí ìpín ìrántí láti dípò àkàrà, àti láti jẹ ẹbọ ọrẹ iná sísun fún Olúwa.

Ka pipe ipin Léfítíkù 24

Wo Léfítíkù 24:7 ni o tọ