Léfítíkù 25:2 BMY

2 “Sọ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, kí o sì wí fún wọn pé: ‘Nígbà tí ẹ bá dé ilẹ̀ náà tí èmi ó fi fún yín: ilẹ̀ náà gbọdọ̀ sinmi fún Olúwa.

Ka pipe ipin Léfítíkù 25

Wo Léfítíkù 25:2 ni o tọ