Léfítíkù 25:5 BMY

5 Ẹ má ṣe kórè ohun tí ó tìkálárarẹ̀ hù: ẹ má ṣe kórè èso àjàrà ọgbà tí ẹ ò tọ́jú. Ilẹ̀ náà gbọdọ̀ ní ìsinmi fún ọdún kan

Ka pipe ipin Léfítíkù 25

Wo Léfítíkù 25:5 ni o tọ