Léfítíkù 27:21 BMY

21 Bí a bá fi ilẹ̀ náà sílẹ̀ ní ọdún ìdásílẹ̀ yóò di mímọ́ gẹ́gẹ́ bí ilẹ̀ tí a fi fún Olúwa. Yóò sì di ohun ìní àlùfáà.

Ka pipe ipin Léfítíkù 27

Wo Léfítíkù 27:21 ni o tọ