Léfítíkù 27:26 BMY

26 “ ‘Kò sí ẹni tí ó gbọdọ̀ ya gbogbo àkọ́bí ẹran sí mímọ́. Èyí jẹ́ ti Olúwa nípaṣẹ̀ òfin àkọ́bí: yálà kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ ni tàbí àgùntàn, ti Olúwa ni.

Ka pipe ipin Léfítíkù 27

Wo Léfítíkù 27:26 ni o tọ