Léfítíkù 27:30 BMY

30 “ ‘Gbogbo ìdámẹ́wàá ilẹ̀ náà yálà tí èso ilẹ̀ ni, tàbí tí èso igi, ti Olúwa ni. Mímọ́ ni fún Olúwa.

Ka pipe ipin Léfítíkù 27

Wo Léfítíkù 27:30 ni o tọ