Léfítíkù 27:32 BMY

32 Gbogbo ìdámẹ́wàá àgbò àti ẹran ọ̀sìn, àní ìdámẹ́wàá ẹran tó bá kọjá lábẹ́ ọ̀pá darandaran kí ó jẹ́ mímọ́ fún Olúwa.

Ka pipe ipin Léfítíkù 27

Wo Léfítíkù 27:32 ni o tọ