Léfítíkù 3:13 BMY

13 Kí ó gbé ọwọ́ lé e lórí. Kí ó sì pa á ní iwájú àgọ́ ìpàdé. Nígbà náà ni àwọn ọmọ Árónì yóò wọ́n ẹ̀jẹ̀ ẹran náà yí pẹpẹ ká.

Ka pipe ipin Léfítíkù 3

Wo Léfítíkù 3:13 ni o tọ