2 Kí ó gbé ọwọ́ rẹ̀ lé e lórí, kí ó sì pa á ní ẹnu ọ̀nà àgọ́ àjọ. Nígbà náà ni àwọn ọmọ Árónì tí í ṣe àlùfáà yóò wọ́n ẹ̀jẹ̀ ẹran náà yí pẹpẹ ká.
Ka pipe ipin Léfítíkù 3
Wo Léfítíkù 3:2 ni o tọ