Léfítíkù 4:24 BMY

24 Kí ó gbé ọwọ́ rẹ̀ lórí ewúrẹ́ náà, kí ó sì pa á níbi tí wọ́n ti ń pa ẹran ẹbọ sísun níwájú Olúwa. Ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ ni.

Ka pipe ipin Léfítíkù 4

Wo Léfítíkù 4:24 ni o tọ