Léfítíkù 7:24 BMY

24 Ẹ lè lo ọ̀rá ẹran tó kú fúnra rẹ̀ tàbí èyí tí ẹranko ìgbẹ́ pa, fún nǹkan mìíràn, ṣùgbọ́n ẹ kò gbọdọ̀ jẹ ẹ́.

Ka pipe ipin Léfítíkù 7

Wo Léfítíkù 7:24 ni o tọ