Léfítíkù 7:35 BMY

35 Èyí ni ìpín tí a yà sọ́tọ̀ fún Árónì àti àwọn ọmọ rẹ̀ nínú ẹbọ tí a finá sun sí Olúwa lọ́jọ́ tí wọ́n mú wọn wá láti sin Olúwa gẹ́gẹ́ bí àlùfáà.

Ka pipe ipin Léfítíkù 7

Wo Léfítíkù 7:35 ni o tọ