Léfítíkù 8:16 BMY

16 Mósè tún mú gbogbo ọ̀rá tó bo nǹkan inú, èyí tó bo ẹ̀dọ̀, kíndìnrín méjèèjì àti ọ̀rá wọn, ó sì sun gbogbo rẹ̀ lórí pẹpẹ.

Ka pipe ipin Léfítíkù 8

Wo Léfítíkù 8:16 ni o tọ