Léfítíkù 9:6 BMY

6 Nígbà náà ni Mósè wí pé, “Ohun tí Olúwa pa láṣẹ fún yín láti ṣe nìyìí, kí ògo Olúwa bá à lè farahàn yín.”

Ka pipe ipin Léfítíkù 9

Wo Léfítíkù 9:6 ni o tọ