Orin Sólómónì 1:4 BMY

4 Fà mí lọ pẹ̀lú rẹ, kí a lọ kíákíáỌba ti mú mi wá sínú yàrá rẹ̀.Àwa yọ̀ inú wa sì dùn sí ọ;a gbé ìfẹ́ rẹ ga ju ọtí wáìnì lọ.Wọ́n fẹ́ ọ nítòótọ́!

Ka pipe ipin Orin Sólómónì 1

Wo Orin Sólómónì 1:4 ni o tọ