Orin Sólómónì 1:5 BMY

5 Èmi dúdú mo sì ní ẹwà.Ẹ̀yin ọmọbìnrin Jérúsálẹ́mù,Dúdú bí àgọ́ KédárìBí àgọ́ aṣọ kọ́tìnnì ti Sólómónì

Ka pipe ipin Orin Sólómónì 1

Wo Orin Sólómónì 1:5 ni o tọ