Orin Sólómónì 5:6 BMY

6 Èmi sí ilẹ̀kùn fún olùfẹ́ mi,ṣùgbọ́n olùfẹ́ mi ti kúrò, ó ti lọọkàn mi gbọgbẹ́ fún lílọ rẹ̀.Mo wá a kiri ṣùgbọ́n, n kò rí i.Mo pè é ṣùgbọ́n, kò dáhùn

Ka pipe ipin Orin Sólómónì 5

Wo Orin Sólómónì 5:6 ni o tọ